ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́

ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́

EULOGICAL FACTS ABOUT ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́

March 20, 2019

ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́ Ò gbé orí Ẹ̀lẹ́mọ̀ṣọ́, Ògbómọ̀ṣọ́ ògbómọjúgun Ọmọ afògbójà Ibi tí wọ́n gbé ń jẹkà, kí wọ́n tó mùkọ yangan. Ògbómọ̀ṣọ́ begotten by Ajilete, where they eat amala gobbling pap. Ògbómọ̀ṣọ́ uses ògbó to fight like devil, if Ògbómọ̀ṣọ́ is done fighting with you and you are insensitive, you will think Ajilete was frolicking with […]

Read More