The stirring anthem tells the story of our rich heritage, patriotism, hard work, and service. Mere listening to the lyrics, you’ll conclude that The Full Oyo State Anthem is appropriate and indeed, we are the Pacesetter.
Asiwaju ni wa
Asiwaju ni wa
Asiwaju ni wa
Asiwaju ni wa
Ipo Asiwaju
Le’ledumare fun wa
Ni ipinle Oyo
Ipinle Oyo
Eje ka se giri
Omo Oyo
Ka te ipa wa mo ise

Ka ba ara wa soro
Ka so ododo
Ka se oun to to, to dara
Ni igba gbogbo
Ni ibi gbogbo
Ni ipinle Oyo
Ko ni reyin o
Loju mi
Ko ni reyin o
Ko ni reyin o
Nigba temi
Ko ni reyin o
Emi a se ohun to to
To dara nibi gbogbo
Nigba Gbogbo
Asiwaju niwa
Asiwaju niwa
Asiwaju niwa

COPYRIGHT
Copyright © 2020 by My Woven Words: No part of this published blogpost and all of its contents may be reproduced, on another platform or webpage without a prior permission from My Woven Words except in the case of brief quotations cited to reference the source of the blogpost and all its content and certain other uses permitted by copyright law.
For permission requests, contact the admin on [email protected], or WhatsApp/Text him on +2347036065752