WATCH AND DOWNLOAD MUSIC VIDEO: OLORUN L’OBA
ADEYINKA CHARLES FT OLA
LYRICS.
Emi Iba l’egberun ahon koto san ore Baba agba,
Iwo dami nide o je k’ota yo mi,
Enu mi yio pokiki Oluwa,
Ogo ni fun oruko re un wo Igba arun san mose Iba ….
V1:-
Olorun l’oba oludande
Olorun mi, alagbara,
Olorun l’oba olufinimona,
Iwo l’olorun mi, atobiju, alagbara olupese.
CHRS:- Olorun l’oba.
Oludande
Olorun l’oba,
Baba mi o alagbara.
V2. What a worthy of man you are the mighty man of war,
The miracle worker,
The bread healer,
The great provider,
The one who was, who is, and is to come, mo ti wo rere aye lo,
Un o re ni to da bi re alagbara laye ati l’orun, Iwo l’atobiju.
CHRS ; add lips **
Oba gbangban gbangban,
Oba latin latin,
Ohun l’oba
Adanimagbe o,
mo mo oruko re oluwa,
Baba mi o alagbara.
V3.
Nigba t’okan mi poruru poruru,
Olorun l’oba,
Ko gbe mi fo alagbara,
Ogbigba tin gba alailara,
Oba tin gba alailenikan,
Afuni masiregun o,
Iwo lo gba mi l’afonifoji egungun gbigbe eeh
Olorun loba.
V4.
Baba mi l’oba to gaju gbogbo aye lo,
Olola julo,
Ologo julo,
Elewa julo,
Oranmonise ti tun fa ya ti,
Oranmolajo saju omo dájò,
O de ba ni lálejò,
tin mu nkan alejo dani,
Baba mi ti o ni jeun tin bo gbogbo wa,
Ayeraye mo fori bale fun Ololajulo.
CHRS :- Add lips2,
You are the mighty mighty man,
Greater than the greatest ayeraye, Baba mi t’olo korin kese,
Olorun l’oba,
Mimo mimo tó lo mimo,
ton wo mimo Baba mi o, eeh alagbara.
Olorun l’oba,
Ogbenu wundia sola,
Ogbenu omo eniyan fowùn,
Gbani ti a sa ya,
Kabiosi eeh Olorun loba
Mo gbe o ga araye, ara orun olorun t’ólo korin kese,
Baba mi o alagbara.
#Sesho on the beat @ 2020.
#Olorun l’oba
#CharlesAdeyink_x_
#OLA …
COPYRIGHT
Copyright © 2020 by My Woven Words: No part of this published blogpost and all of its contents may be reproduced, on another platform or webpage without a prior permission from My Woven Words except in the case of brief quotations cited to reference the source of the blogpost and all its content and certain other uses permitted by copyright law.
For permission requests, contact the admin on [email protected], or WhatsApp/Text him on +2347036065752